Diutarónómì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìrìn ọjọ́ mọ́kànlá (11) ni láti Hórébù sí Kadeṣi-bánéà+ tí wọ́n bá gba ọ̀nà Òkè Séírì.