- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 15:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 Tó bá jẹ́ àgbò lo fẹ́ fi rúbọ, kí o mú ọrẹ ọkà wá, kí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ìdá méjì nínú mẹ́wàá ìyẹ̀fun tó kúnná, tí o pò mọ́ òróró ìdá mẹ́ta òṣùwọ̀n hínì. 7 Kí o sì mú wáìnì wá láti ṣe ọrẹ ohun mímu, kó jẹ́ ìdá mẹ́ta òṣùwọ̀n hínì, láti mú òórùn dídùn* jáde sí Jèhófà. 
 
-