- 
	                        
            
            Léfítíkù 23:24, 25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        24 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ní ọjọ́ kìíní oṣù keje, kí ẹ sinmi, kí ẹ má ṣiṣẹ́ kankan, kí ẹ fi ìró kàkàkí+ kéde rẹ̀ láti máa rántí, yóò jẹ́ àpéjọ mímọ́. 25 Ẹ má ṣiṣẹ́ agbára kankan, kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.’” 
 
-