Nọ́ńbà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ṣe kàkàkí+ méjì fún ara rẹ, fàdákà tí wọ́n fi òòlù lù ni kí o fi ṣe é. Kí o máa fi pe àwọn èèyàn náà jọ pọ̀, kí o sì máa fi sọ fún wọn pé kí wọ́n tú àgọ́ wọn ká. Sáàmù 81:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ fun ìwo nígbà òṣùpá tuntun,+Nígbà òṣùpá àrànmọ́jú, nítorí ọjọ́ àjọyọ̀ wa.+
2 “Ṣe kàkàkí+ méjì fún ara rẹ, fàdákà tí wọ́n fi òòlù lù ni kí o fi ṣe é. Kí o máa fi pe àwọn èèyàn náà jọ pọ̀, kí o sì máa fi sọ fún wọn pé kí wọ́n tú àgọ́ wọn ká.