- 
	                        
            
            Jẹ́nẹ́sísì 48:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        20 Ó sì súre fún wọn ní ọjọ́+ yẹn, ó ní: “Kí Ísírẹ́lì máa fi orúkọ rẹ súre pé, ‘Kí Ọlọ́run mú kí o dà bí Éfúrémù àti Mánásè.’” Ó wá ń fi Éfúrémù ṣáájú Mánásè. 
 
-