- 
	                        
            
            Léfítíkù 23:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        36 Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. Ní ọjọ́ kẹjọ, kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́,+ kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. Àpéjọ ọlọ́wọ̀ ni. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára kankan. 
 
-