Léfítíkù 7:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Tí ohun tó bá fi rúbọ bá jẹ́ ti ẹ̀jẹ́+ tàbí ọrẹ àtinúwá,+ ọjọ́ tó bá mú ọrẹ rẹ̀ wá ni kó jẹ ẹ́, kó sì jẹ ohun tó bá ṣẹ́ kù lára rẹ̀ ní ọjọ́ kejì. Léfítíkù 22:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “‘Tí ẹnì kan bá mú ẹran ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ wá fún Jèhófà kó lè fi san ẹ̀jẹ́ tàbí kó lè fi ṣe ọrẹ àtinúwá, ẹran tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá ni kó mú wá látinú ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo ẹran, kó lè rí ìtẹ́wọ́gbà. Ẹran náà ò gbọ́dọ̀ ní àbùkù kankan.
16 “‘Tí ohun tó bá fi rúbọ bá jẹ́ ti ẹ̀jẹ́+ tàbí ọrẹ àtinúwá,+ ọjọ́ tó bá mú ọrẹ rẹ̀ wá ni kó jẹ ẹ́, kó sì jẹ ohun tó bá ṣẹ́ kù lára rẹ̀ ní ọjọ́ kejì.
21 “‘Tí ẹnì kan bá mú ẹran ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ wá fún Jèhófà kó lè fi san ẹ̀jẹ́ tàbí kó lè fi ṣe ọrẹ àtinúwá, ẹran tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá ni kó mú wá látinú ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo ẹran, kó lè rí ìtẹ́wọ́gbà. Ẹran náà ò gbọ́dọ̀ ní àbùkù kankan.