- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 15:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Kí o tún fi wáìnì ṣe ọrẹ ohun mímu, kó jẹ́ ìlàrin òṣùwọ̀n hínì pẹ̀lú ẹbọ sísun+ náà tàbí pẹ̀lú ẹbọ kọ̀ọ̀kan tí ẹ fi akọ ọ̀dọ́ àgùntàn ṣe. 
 
-