ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 13:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Wọ́n sì ń ròyìn ohun tí kò dáa+ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nípa ilẹ̀ tí wọ́n lọ ṣe amí rẹ̀, wọ́n ní: “Ilẹ̀ tó ń jẹ àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ run ni ilẹ̀ tí a lọ ṣe amí rẹ̀, gbogbo àwọn èèyàn tí a sì rí níbẹ̀ ló tóbi yàtọ̀.+

  • Diutarónómì 1:26-28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Àmọ́ ẹ kọ̀ láti gòkè lọ, ẹ sì kọ̀ láti tẹ̀ lé àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run yín.+ 27 Ẹ̀ ń ráhùn ṣáá nínú àwọn àgọ́ yín, ẹ sì ń sọ pé, ‘Torí Jèhófà kórìíra wa ló ṣe mú wa kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì láti fi wá lé àwọn Ámórì lọ́wọ́, kí wọ́n lè pa wá run. 28 Báwo ni ibi tí à ń lọ ṣe rí? Àwọn arákùnrin wa mú kí ẹ̀rù bà wá,*+ wọ́n sọ pé: “Àwọn èèyàn náà lágbára, wọ́n sì ga jù wá lọ, àwọn ìlú wọn tóbi, wọ́n sì mọ odi rẹ̀ kan ọ̀run,*+ a sì rí àwọn ọmọ Ánákímù+ níbẹ̀.”’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́