- 
	                        
            Ẹ́kísódù 15:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        27 Lẹ́yìn náà, wọ́n dé Élímù, níbi tí ìsun omi méjìlá (12) àti àádọ́rin (70) igi ọ̀pẹ wà. Wọ́n sì pàgọ́ síbẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ omi náà. 
 
- 
                                        
27 Lẹ́yìn náà, wọ́n dé Élímù, níbi tí ìsun omi méjìlá (12) àti àádọ́rin (70) igi ọ̀pẹ wà. Wọ́n sì pàgọ́ síbẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ omi náà.