ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 18:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Jẹ́tírò, bàbá ìyàwó Mósè, pẹ̀lú àwọn ọmọ Mósè àti ìyàwó rẹ̀ wá bá Mósè ní aginjù níbi tó pàgọ́ sí, ní òkè Ọlọ́run tòótọ́.+

  • Ẹ́kísódù 19:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ní ọjọ́ tó pé oṣù mẹ́ta tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, wọ́n dé aginjù Sínáì. 2 Wọ́n ṣí kúrò ní Réfídímù,+ wọ́n dé aginjù Sínáì, wọ́n sì pàgọ́ sí aginjù náà. Ísírẹ́lì pàgọ́ síbẹ̀ níwájú òkè náà.+

  • Nọ́ńbà 1:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 1 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní aginjù Sínáì,+ nínú àgọ́ ìpàdé,+ ní ọjọ́ kìíní oṣù kejì, ọdún kejì tí wọ́n kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Ó sọ pé:

  • Nọ́ńbà 3:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àmọ́ Nádábù àti Ábíhù kú níwájú Jèhófà nígbà tí wọ́n rú ẹbọ tí kò tọ́ níwájú Jèhófà+ ní aginjù Sínáì, wọn ò sì bímọ kankan. Àmọ́ Élíásárì+ àti Ítámárì+ ṣì ń ṣiṣẹ́ àlùfáà pẹ̀lú Áárónì bàbá wọn.

  • Nọ́ńbà 9:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní aginjù Sínáì ní oṣù kìíní,+ ọdún kejì tí wọ́n kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, ó sọ pé:

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́