Diutarónómì 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n gbéra láti ibẹ̀ lọ sí Gúdígódà, láti Gúdígódà lọ sí Jótíbátà,+ ilẹ̀ tó ní àwọn odò tó ń ṣàn.*