-
Nọ́ńbà 4:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Kí o forúkọ wọn sílẹ̀ láti ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún sí àádọ́ta (50) ọdún, gbogbo ẹni tó wà lára àwọn tí a yàn pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìpàdé.
-