-
Ẹ́kísódù 19:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Sọ̀ kalẹ̀, kí o lọ kìlọ̀ fún àwọn èèyàn náà pé kí wọ́n má fi dandan wá ọ̀nà láti wo Jèhófà, kí ọ̀pọ̀ nínú wọn má bàa pa run.
-