-
Ẹ́kísódù 26:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Kí o fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe òpó márùn-ún fún aṣọ* náà, kí o sì fi wúrà bo àwọn òpó náà. Kí o fi wúrà ṣe àwọn ìkọ́ wọn, kí o sì fi bàbà ṣe ìtẹ́lẹ̀ márùn-ún tó ní ihò fún wọn.
-
-
Ẹ́kísódù 36:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 pẹ̀lú òpó rẹ̀ márùn-ún àti àwọn ìkọ́ wọn. Ó fi wúrà bo orí wọn àti àwọn ohun tó so wọ́n pọ̀,* àmọ́ bàbà ló fi ṣe ìtẹ́lẹ̀ oníhò wọn márààrún.
-