Nọ́ńbà 4:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Èyí ni iṣẹ́ tí ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì á máa ṣe nínú àgọ́ ìpàdé,+ Ítámárì+ ọmọ àlùfáà Áárónì ni yóò sì máa darí iṣẹ́ wọn.
28 Èyí ni iṣẹ́ tí ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì á máa ṣe nínú àgọ́ ìpàdé,+ Ítámárì+ ọmọ àlùfáà Áárónì ni yóò sì máa darí iṣẹ́ wọn.