-
Nọ́ńbà 3:27, 28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ọ̀dọ̀ Kóhátì ni ìdílé àwọn ọmọ Ámúrámù ti ṣẹ̀ wá, pẹ̀lú ìdílé àwọn ọmọ Ísárì, ìdílé àwọn ọmọ Hébúrónì àti ìdílé àwọn ọmọ Úsíélì. Ìwọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì.+ 28 Gbogbo ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ oṣù kan sókè jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́jọ ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (8,600); ojúṣe wọn ni pé kí wọ́n máa bójú tó ibi mímọ́.+
-