-
Léfítíkù 5:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 “‘Tó bá jẹ̀bi torí pé ó ṣe ọ̀kan nínú àwọn nǹkan yìí, kó jẹ́wọ́+ èyí tó ṣe gan-an.
-
-
Jóṣúà 7:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Jóṣúà wá sọ fún Ákánì pé: “Ọmọ mi, jọ̀ọ́, bọlá fún Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, kí o sì jẹ́wọ́ fún un. Jọ̀ọ́, sọ ohun tí o ṣe fún mi. Má fi pa mọ́ fún mi.”
-