-
Nọ́ńbà 5:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 kí ọkùnrin náà mú ìyàwó rẹ̀ wá sọ́dọ̀ àlùfáà, kó mú ọrẹ dání fún un, ìyẹ̀fun ọkà bálì tó kún ìdá mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà.* Kó má da òróró sí i, kó má sì fi oje igi tùràrí sórí rẹ̀, torí ọrẹ ọkà owú ni, ọrẹ ọkà tó ń múni rántí ẹ̀bi.
-
-
Nọ́ńbà 5:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Kí àlùfáà wá gba ọrẹ ọkà owú+ náà lọ́wọ́ obìnrin náà, kó fi ọrẹ ọkà náà síwá-sẹ́yìn níwájú Jèhófà, kó wá gbé e sún mọ́ pẹpẹ.
-