-
2 Sámúẹ́lì 6:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Nígbà tí àwọn tó ń ru+ Àpótí Jèhófà gbé ẹsẹ̀ mẹ́fà, ó fi akọ màlúù kan àti ẹran àbọ́sanra kan rúbọ.
-
-
1 Kíróníkà 15:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nígbà náà, àwọn ọmọ Léfì fi àwọn ọ̀pá+ gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ lé èjìká wọn, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Mósè pa látọ̀dọ̀ Jèhófà.
-