-
Nọ́ńbà 2:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Kí ẹ̀yà Sébúlúnì wá tẹ̀ lé wọn; Élíábù+ ọmọ Hélónì ni ìjòyè àwọn ọmọ Sébúlúnì.
-
-
Nọ́ńbà 10:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Élíábù+ ọmọ Hélónì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Sébúlúnì.
-