-
Ẹ́kísódù 40:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Ní ọjọ́ kìíní oṣù kìíní, kí o to àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ ìpàdé náà.+
-
-
Ẹ́kísódù 40:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ní ọjọ́ kìíní, oṣù kìíní, ọdún kejì, wọ́n to àgọ́ ìjọsìn náà.+
-