-
Nọ́ńbà 9:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Tí Jèhófà bá pàṣẹ pé kí wọ́n pàgọ́, wọ́n á pàgọ́. Tí Jèhófà bá sì pàṣẹ pé kí wọ́n gbéra, wọ́n á gbéra. Wọ́n ń ṣe ojúṣe wọn sí Jèhófà bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.
-