ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 12:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá kúrò ní Rámésésì,+ wọ́n sì forí lé Súkótù,+ wọ́n tó nǹkan bí ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ (600,000) ọkùnrin tó ń fẹsẹ̀ rìn, yàtọ̀ sí àwọn ọmọdé.+

  • Ẹ́kísódù 38:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Ìlàjì ṣékélì tó jẹ́ ìwọ̀n ṣékélì ibi mímọ́* ni ìlàjì ṣékélì ẹnì kọ̀ọ̀kan, ìyẹn gbogbo ẹni tó wà lára àwọn tó forúkọ sílẹ̀ láti ẹni ogún (20) ọdún sókè,+ wọ́n jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ààbọ̀ àti àádọ́ta (603,550).+

  • Nọ́ńbà 1:45, 46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 45 Gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ ẹni ogún (20) ọdún sókè tó lè dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì ni wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ bí wọ́n ṣe wà nínú agbo ilé bàbá wọn, 46 gbogbo àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ sì jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ó lé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ààbọ̀ àti àádọ́ta (603,550).+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́