ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 10:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ẹ̀mí Jèhófà yóò fún ọ lágbára,+ wàá máa sọ tẹ́lẹ̀ pẹ̀lú wọn, wàá sì yàtọ̀ sí ẹni tí o jẹ́ tẹ́lẹ̀.+

  • 1 Sámúẹ́lì 19:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ní kíá, Sọ́ọ̀lù rán àwọn òjíṣẹ́ láti lọ mú Dáfídì. Nígbà tí wọ́n rí àwọn tó dàgbà lára àwọn wòlíì tí wọ́n ń sọ tẹ́lẹ̀, tí Sámúẹ́lì sì dúró tó ń ṣe olórí wọn, ẹ̀mí Ọlọ́run bà lé àwọn òjíṣẹ́ Sọ́ọ̀lù, àwọn náà sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe bíi wòlíì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́