Sáàmù 78:30, 31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Àmọ́ kí wọ́n tó tẹ́ ìfẹ́ ọkàn wọn lọ́rùn pátápátá,Nígbà tí oúnjẹ wọn ṣì wà lẹ́nu wọn, 31 Ìbínú Ọlọ́run ru sí wọn.+ Ó pa àwọn ọkùnrin wọn tó lágbára jù lọ;+Ó mú àwọn ọ̀dọ́kùnrin Ísírẹ́lì balẹ̀. 1 Kọ́ríńtì 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bákan náà, kí ẹ má ṣe máa kùn, bí àwọn kan nínú wọn ṣe kùn,+ tí apanirun sì pa wọ́n.+
30 Àmọ́ kí wọ́n tó tẹ́ ìfẹ́ ọkàn wọn lọ́rùn pátápátá,Nígbà tí oúnjẹ wọn ṣì wà lẹ́nu wọn, 31 Ìbínú Ọlọ́run ru sí wọn.+ Ó pa àwọn ọkùnrin wọn tó lágbára jù lọ;+Ó mú àwọn ọ̀dọ́kùnrin Ísírẹ́lì balẹ̀.