1 Kọ́ríńtì 10:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn nǹkan yìí di àpẹẹrẹ fún wa, kí àwọn ohun tó ń ṣeni léṣe má bàa máa wu àwa náà, bó ṣe wù wọ́n.+
6 Àwọn nǹkan yìí di àpẹẹrẹ fún wa, kí àwọn ohun tó ń ṣeni léṣe má bàa máa wu àwa náà, bó ṣe wù wọ́n.+