-
Nọ́ńbà 11:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Àwọn èèyàn náà kúrò ní Kiburoti-hátááfà lọ sí Hásérótì, wọ́n sì dúró sí Hásérótì.+
-
-
Nọ́ńbà 33:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Lẹ́yìn náà, wọ́n kúrò ní Hásérótì, wọ́n sì pàgọ́ sí Rítímà.
-