Diutarónómì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Lẹ́yìn náà, a kúrò ní Hórébù, a sì kọjá ní gbogbo aginjù tí ó tóbi tó sì ń bani lẹ́rù yẹn,+ èyí tí ẹ rí lójú ọ̀nà tó lọ sí agbègbè olókè àwọn Ámórì,+ bí Jèhófà Ọlọ́run wa ṣe pàṣẹ fún wa gẹ́lẹ́, a sì wá dé Kadeṣi-bánéà.+
19 “Lẹ́yìn náà, a kúrò ní Hórébù, a sì kọjá ní gbogbo aginjù tí ó tóbi tó sì ń bani lẹ́rù yẹn,+ èyí tí ẹ rí lójú ọ̀nà tó lọ sí agbègbè olókè àwọn Ámórì,+ bí Jèhófà Ọlọ́run wa ṣe pàṣẹ fún wa gẹ́lẹ́, a sì wá dé Kadeṣi-bánéà.+