-
Diutarónómì 1:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Wọ́n mú lára èso ilẹ̀ náà, wọ́n sì kó o wá fún wa, wọ́n pa dà wá jábọ̀ fún wa pé, ‘Ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run wa fẹ́ fún wa dáa.’+
-