-
Nọ́ńbà 1:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Wọ́n fi orúkọ wọn, ìdílé wọn àti agbo ilé bàbá wọn to àwọn ọmọkùnrin Rúbẹ́nì, àwọn àtọmọdọ́mọ àkọ́bí+ Ísírẹ́lì. Gbogbo ọkùnrin tó jẹ́ ẹni ogún (20) ọdún sókè, tó lè dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun ni wọ́n kà lọ́kọ̀ọ̀kan,
-