Nọ́ńbà 13:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 nínú ẹ̀yà Éfúrémù, Hóṣéà+ ọmọ Núnì; Nọ́ńbà 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Èyí ni orúkọ àwọn ọkùnrin tí Mósè rán láti ṣe amí ilẹ̀ náà. Mósè wá sọ Hóṣéà ọmọ Núnì ní Jóṣúà.*+