Sáàmù 72:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kí á yin orúkọ rẹ̀ ológo títí láé,+Kí ògo rẹ̀ sì kún gbogbo ayé.+ Àmín àti Àmín. Hábákúkù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí gbogbo ayé yóò ní ìmọ̀ nípa ògo Jèhófà Bí ìgbà tí omi bo òkun.+