- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan, kí ìjòyè kọ̀ọ̀kan mú ọrẹ rẹ̀ wá fún ìyàsímímọ́ pẹpẹ náà, ní ọjọ́ kan tẹ̀ lé òmíràn.” 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 7:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        36 Ní ọjọ́ karùn-ún, Ṣẹ́lúmíẹ́lì+ ọmọ Súríṣádáì, ìjòyè àwọn ọmọ Síméónì, 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 10:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        19 Ṣẹ́lúmíẹ́lì+ ọmọ Súríṣádáì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Síméónì. 
 
-