-
Jóṣúà 14:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Mósè búra ní ọjọ́ yẹn pé: ‘Ilẹ̀ tí o fi ẹsẹ̀ rẹ tẹ̀ máa di ogún ìwọ àtàwọn ọmọ rẹ títí lọ, torí pé o ti fi gbogbo ọkàn rẹ tẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run mi.’+
-
-
Jóṣúà 14:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ìdí nìyẹn tí Hébúrónì fi jẹ́ ogún Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè ọmọ Kénásì títí dòní, torí ó fi gbogbo ọkàn rẹ̀ tẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+
-