Ẹ́kísódù 6:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Màá mú yín wá sí ilẹ̀ tí mo búra* pé màá fún Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù; màá sì mú kó di ohun ìní yín.+ Èmi ni Jèhófà.’”+
8 Màá mú yín wá sí ilẹ̀ tí mo búra* pé màá fún Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù; màá sì mú kó di ohun ìní yín.+ Èmi ni Jèhófà.’”+