Nọ́ńbà 14:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Inú aginjù yìí lẹ máa kú sí,+ àní gbogbo àwọn tó jẹ́ ẹni ogún (20) ọdún sókè nínú yín, àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ kùn sí mi.+ Hébérù 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bákan náà, àwọn wo ni ọ̀rọ̀ wọn kó Ọlọ́run nírìíra fún ogójì (40) ọdún?+ Ṣebí àwọn tó dẹ́ṣẹ̀, tí òkú wọn sùn nínú aginjù ni?+
29 Inú aginjù yìí lẹ máa kú sí,+ àní gbogbo àwọn tó jẹ́ ẹni ogún (20) ọdún sókè nínú yín, àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ kùn sí mi.+
17 Bákan náà, àwọn wo ni ọ̀rọ̀ wọn kó Ọlọ́run nírìíra fún ogójì (40) ọdún?+ Ṣebí àwọn tó dẹ́ṣẹ̀, tí òkú wọn sùn nínú aginjù ni?+