Nọ́ńbà 13:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Wọ́n sì ń ròyìn ohun tí kò dáa+ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nípa ilẹ̀ tí wọ́n lọ ṣe amí rẹ̀, wọ́n ní: “Ilẹ̀ tó ń jẹ àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ run ni ilẹ̀ tí a lọ ṣe amí rẹ̀, gbogbo àwọn èèyàn tí a sì rí níbẹ̀ ló tóbi yàtọ̀.+
32 Wọ́n sì ń ròyìn ohun tí kò dáa+ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nípa ilẹ̀ tí wọ́n lọ ṣe amí rẹ̀, wọ́n ní: “Ilẹ̀ tó ń jẹ àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ run ni ilẹ̀ tí a lọ ṣe amí rẹ̀, gbogbo àwọn èèyàn tí a sì rí níbẹ̀ ló tóbi yàtọ̀.+