- 
	                        
            
            Léfítíkù 1:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        2 “Bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* sọ̀rọ̀, kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Tí ẹnikẹ́ni nínú yín bá fẹ́ fi ẹran ọ̀sìn ṣe ọrẹ fún Jèhófà, kó mú ọrẹ rẹ̀ wá látinú ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo ẹran.+ 3 “‘Tó bá fẹ́ mú ẹran wá láti fi rú ẹbọ sísun látinú ọ̀wọ́ ẹran, kó jẹ́ akọ tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá.+ Tinútinú+ ni kó mú un wá síwájú Jèhófà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé. 
 
-