- 
	                        
            
            Léfítíkù 4:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        20 Ohun tó ṣe sí akọ màlúù kejì tó jẹ́ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni kó ṣe sí akọ màlúù náà. Bó ṣe máa ṣe é nìyẹn, kí àlùfáà ṣe ètùtù fún wọn,+ wọ́n á sì rí ìdáríjì. 
 
-