Ìsíkíẹ́lì 18:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọkàn* tó bá ṣẹ̀ ni yóò kú.+ Ọmọ ò ní ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ bàbá rẹ̀, bàbá ò sì ní ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ rẹ̀. Olódodo máa jèrè òdodo rẹ̀, ẹni burúkú sì máa jèrè ìwà burúkú rẹ̀.+
20 Ọkàn* tó bá ṣẹ̀ ni yóò kú.+ Ọmọ ò ní ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ bàbá rẹ̀, bàbá ò sì ní ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ rẹ̀. Olódodo máa jèrè òdodo rẹ̀, ẹni burúkú sì máa jèrè ìwà burúkú rẹ̀.+