1 Kọ́ríńtì 14:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Nítorí Ọlọ́run kì í ṣe Ọlọ́run rúdurùdu, bí kò ṣe ti àlàáfíà.+ Gẹ́gẹ́ bó ṣe rí nínú gbogbo ìjọ àwọn ẹni mímọ́, 1 Kọ́ríńtì 14:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Àmọ́ ẹ jẹ́ kí ohun gbogbo máa ṣẹlẹ̀ lọ́nà tó bójú mu àti létòlétò.*+
33 Nítorí Ọlọ́run kì í ṣe Ọlọ́run rúdurùdu, bí kò ṣe ti àlàáfíà.+ Gẹ́gẹ́ bó ṣe rí nínú gbogbo ìjọ àwọn ẹni mímọ́,