Júùdù 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó mà ṣe o, wọ́n tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Kéènì.+ Láìronú, wọ́n ṣe ohun tí kò tọ́ bíi ti Báláámù+ torí ohun tí wọ́n máa rí gbà, ọ̀rọ̀ ọ̀tẹ̀+ wọn sì mú kí wọ́n ṣègbé bíi ti Kórà!+
11 Ó mà ṣe o, wọ́n tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Kéènì.+ Láìronú, wọ́n ṣe ohun tí kò tọ́ bíi ti Báláámù+ torí ohun tí wọ́n máa rí gbà, ọ̀rọ̀ ọ̀tẹ̀+ wọn sì mú kí wọ́n ṣègbé bíi ti Kórà!+