-
Diutarónómì 18:21, 22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àmọ́, ẹ lè sọ lọ́kàn yín pé: “Báwo la ṣe máa mọ̀ pé Jèhófà kọ́ ló sọ ọ̀rọ̀ náà fún un?” 22 Tí wòlíì náà bá sọ̀rọ̀ lórúkọ Jèhófà, tí ọ̀rọ̀ náà kò sì ṣẹ tàbí tí ohun tó sọ kò ṣẹlẹ̀, á jẹ́ pé Jèhófà kọ́ ló sọ ọ̀rọ̀ náà. Ìkọjá àyè ló mú kó sọ ọ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ bẹ̀rù rẹ̀.’
-