Nọ́ńbà 16:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun tí ẹ máa ṣe nìyí: Kí ìwọ Kórà àti gbogbo àwọn tó ń tì ọ́ lẹ́yìn+ mú ìkóná,+ 7 kí ẹ fi iná sí i, kí ẹ sì fi tùràrí sí i níwájú Jèhófà lọ́la, ẹni tí Jèhófà bá sì yàn,+ òun ni ẹni mímọ́. “Ó tó gẹ́ẹ́, ẹ̀yin ọmọ Léfì!”+
6 Ohun tí ẹ máa ṣe nìyí: Kí ìwọ Kórà àti gbogbo àwọn tó ń tì ọ́ lẹ́yìn+ mú ìkóná,+ 7 kí ẹ fi iná sí i, kí ẹ sì fi tùràrí sí i níwájú Jèhófà lọ́la, ẹni tí Jèhófà bá sì yàn,+ òun ni ẹni mímọ́. “Ó tó gẹ́ẹ́, ẹ̀yin ọmọ Léfì!”+