ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 16:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ní àárọ̀, ẹ máa rí ògo Jèhófà, torí Jèhófà ti gbọ́ bí ẹ ṣe ń kùn sí òun. Ta ni àwa jẹ́ tí ẹ ó fi máa kùn sí wa?”

  • Nọ́ńbà 14:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Síbẹ̀, gbogbo àwọn èèyàn náà sọ pé àwọn máa sọ wọ́n lókùúta.+ Àmọ́ ògo Jèhófà fara han gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ lórí àgọ́ ìpàdé.

  • Nọ́ńbà 16:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Nígbà tí Kórà kó àwọn tó ń tì í lẹ́yìn,+ tí wọ́n jọ ń ta kò wọ́n jọ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà fara han gbogbo àpéjọ+ náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́