-
Nọ́ńbà 20:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ó ṣẹlẹ̀ pé kò sí omi fún àpéjọ+ náà, wọ́n bá kóra jọ lòdì sí Mósè àti Áárónì.
-
-
Nọ́ńbà 20:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Mósè àti Áárónì wá kúrò níwájú ìjọ náà lọ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, wọ́n wólẹ̀, ògo Jèhófà sì bẹ̀rẹ̀ sí í fara hàn wọ́n.+
-