-
Nọ́ńbà 11:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àwọn èèyàn náà bá bẹ̀rẹ̀ sí í ráhùn gidigidi níwájú Jèhófà. Nígbà tí Jèhófà gbọ́, inú bí i gan-an, iná sì wá látọ̀dọ̀ Jèhófà, ó jó àwọn kan tó wà ní ìkángun ibùdó náà run.
-
-
Nọ́ńbà 16:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Torí náà, ṣe ni ìwọ àti gbogbo àwọn tó wà lẹ́yìn rẹ tí ẹ kóra yín jọ ń bá Jèhófà jà. Kí wá ni ti Áárónì, tí ẹ fi ń kùn sí i?”+
-