Nọ́ńbà 16:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Kí ẹ fi ìkóná àwọn èèyàn tó ṣẹ̀ tí wọ́n sì fi ẹ̀mí ara wọn dí i ṣe àwọn irin pẹlẹbẹ tí ẹ máa fi bo pẹpẹ,+ torí iwájú Jèhófà ni wọ́n mú un wá, ó sì ti di mímọ́. Kó máa jẹ́ àmì fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.”+
38 Kí ẹ fi ìkóná àwọn èèyàn tó ṣẹ̀ tí wọ́n sì fi ẹ̀mí ara wọn dí i ṣe àwọn irin pẹlẹbẹ tí ẹ máa fi bo pẹpẹ,+ torí iwájú Jèhófà ni wọ́n mú un wá, ó sì ti di mímọ́. Kó máa jẹ́ àmì fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.”+