ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 3:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Jẹ́ kí ẹ̀yà Léfì+ wá síwájú, kí o sì ní kí wọ́n dúró níwájú àlùfáà Áárónì, kí wọ́n máa ṣe ìránṣẹ́+ fún un.

  • Nọ́ńbà 8:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Léfì wọlé kí wọ́n lè máa ṣe iṣẹ́ wọn nínú àgọ́ ìpàdé níwájú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀. Ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè nípa àwọn ọmọ Léfì ni wọ́n ṣe fún wọn gẹ́lẹ́.

  • Nọ́ńbà 16:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ṣé ohun kékeré lẹ rò pé Ọlọ́run Ísírẹ́lì ṣe fún yín, bó ṣe yà yín sọ́tọ̀ nínú àpéjọ Ísírẹ́lì,+ tó ń jẹ́ kí ẹ máa wá síwájú òun láti máa ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìjọsìn Jèhófà, kí ẹ sì máa dúró níwájú àpéjọ láti máa ṣe ìránṣẹ́ fún wọn,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́